Ago Onile
5
views
Lyrics
Àgò onílé, a mà dé, àwa ni (ẹyin wo nùu?) ♪ Àgò onílé, a mà dé, àwa ni (ẹ káàbọ' o!) ♪ Àgò onílé, a mà dé, àwa ni (a tí ń retí yín!) ♪ Àgò onílé, a mà dé, àwa ni (ẹ má wo 'lẹ' o!) ♪ Àgò onílé, a mà dé, àwa ní ♪ A dé, mo seb'á'wa náà ni, ẸniỌ'bánkẹ' gangan, a tún dé Ati tún dé o A ma dé o, kò s'éwu l'ẹ'gbẹ'rún ẹ'kọ, ẹ máa bá wa kálọ, a tún dé Láti ilé ọgbọn A dé, seb'á'wa náà ni, ọmọ ọ'dọ' àgbàgbà, a tún dé Ẹni bá ṣe 're Ire ni ó ma rí, ẹni bá sì ṣè 'kà, àbámọ' ni ó jẹ l'óde, ayé Ẹ f'ìwà ṣ'ọlá Ẹ f'ọlá m'ẹbí, f'owó m'aráàdúgbò, ẹnìkan ò m'ẹ'hìn ọ'la, ẹ yé Tẹẹ' jẹ'jẹ' Yíyí l'ayé ń yí, ẹní kàn l'ọ'tẹ' yìí, ẹ' bá jẹ' a rọra ṣ'ayé F'òtítọ' ṣ'ọ'rẹ' K'áyé ó le r'ójú, ẹ jẹ' á tún 'lẹ' yìí ṣe, k'ára ó rọ gbogbo wa, ẹ yé! ♪ Àgò onílé a mà dé àwa ni
Audio Features
Song Details
- Duration
- 04:46
- Key
- 1
- Tempo
- 93 BPM
Share
More Songs by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Albums by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Similar Songs
Araromi
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Atunda Ere
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Gedegbe
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Abanije
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Afurugbin
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Ijo Oni
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band