B'o Se Nd'agba
3
views
Lyrics
Bí'nú rẹ bá dùn k'o rọra ṣe L'ọ'jọ' ìkorò má fa'jú ro Kò sí b'ọ'nà ṣe gbòrò tó, gbángungbàngun díẹ' yí ó wà níbẹ' o Bo r'ẹ'ni nyọ' k'o bá wọn ṣe, ẹni ń sunkún ò, fà wọn mọ'ra Àní b'o ṣe ń d'àgbà, ọmọ, má ṣe k'ẹ'gbẹ' olókùnkùn M'ọ'wọ' rẹ s'óun rere ṣe Mo ní b'o ṣe ń g'òkè ìlérí, má gbàgbé ìbẹ'rẹ' M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe ♪ B'o l'ọ'rọ' púpọ' má fi ṣ'akọ, bí ò sí o, má ṣè'lara Kò sí b'ọ'nà ṣe gbòrò tó, gbángungbàngun díẹ' yí ó wà níbẹ' o Àríyọ' mi ò, ọmọ rere, ìtùnú òbí rẹ' l'ọ'jọ' ogbó Àní b'o ṣe ń d'àgbà, ọmọ Akin, má ro'jú, má ṣ'ọ'le M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe Mo ní b'ẹ ṣe ń d'àgbà, ọmọ, má ṣe kún wọn ní'gbìmọ' ọ'tẹ' M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe Moní b'o ṣe ń làkàkà, ọmọ, má ro'jú, má ṣ'ọ'le M'ọ'wọ' rẹ s'óun rere ṣe Kò sí b'ọ'nà ṣe gbòrò tó, gbángungbàngun díẹ' yí ó wà níbẹ' o Àní b'o ṣe ń d'àgbà, ọmọ, má ṣe k'ẹ'gbẹ' olókùnkùn M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe Mo ní b'o ṣe ń g'òkè ìlérí, má gbàgbé ìbẹ'rẹ' M'ọ'wọ' rẹ s'óun réré ṣe
Audio Features
Song Details
- Duration
- 04:20
- Key
- 1
- Tempo
- 109 BPM
Share
More Songs by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Albums by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Similar Songs
Araromi
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Atunda Ere
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Gedegbe
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Ijo Oni
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Abanije
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Afurugbin
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band