Harvestime

5 views

Lyrics

You know the truth they say will set you free
 And if you play it right, you win the game
 The race is not for those who are swift
 The crown will be won by those who wait
 Mó ṣe b'ẹyin lẹ l'òní o, ẹ dẹ' ńṣì'wà wù
 Ẹni tó l'ọ'la ńbọ' l'ọ'nà, wọn ń sá'ré o
 Ọba tó l'ọjọ' gbogbo kìi mà í sùn
 Ẹni t'ó mòye, a bẹ' yín o, kẹ'ẹ tẹ'tí
 ♪
 So, you can sow your seed and watch it grow
 Harvestime is near and you will see
 It wouldn't matter who you know or seek
 Time is up and you will pay the price
 Ọrẹ mi ta'fà s'ókè, f'odó b'orí
 Ẹ'san ò ní s'àì ké, ó lè pẹ' o, kóo gbọ'
 Àarígiṣégi, mọ'dàrú, àpà, ọ'bàyẹ'jẹ'
 Ìgbà ọtun mà dé tán, mo mà ńw'ọnà, k'ẹ gbọ o
 ♪
 Mo ṣe b'ẹyin lẹ l'òní o, ẹ dẹ' ńṣì'wà wù
 Ẹni tó lọla ńbọ' l'ọ'nà, wọn ńsá'ré o
 Ọba tó l'ọjọ' gbogbo, kìi mà í sùn
 Ẹni t'ó mòye, a bẹ' yín o, k'ẹẹ tẹ'tí
 Òtítọ' korò, yé o, kò dùn l'étí
 Ọrọ' ẹtàn ìyẹn mà ló pọ' jù, ọrẹ o
 Ẹni a wí fún, ọba, mà jẹ' ó gbọ' o
 Èyí a kìlọ' fún, mà jẹ' ó gbà l'ásìkò
 Mo ṣe b'ẹyin lẹ l'òní o, ẹ dẹ' ńṣì'wà wù
 Ẹni tó l'ọ'la nbọ' l'ọnà, wọn ńsá'ré o
 Ọba tó l'ọjọ' gbogbo, ke mà í sùn
 Ẹ'san ìkà lè pẹ, sùgbọn, o ńbọ', kẹẹ gbọ' o
 

Audio Features

Song Details

Duration
03:55
Key
2
Tempo
120 BPM

Share

More Songs by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

Albums by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

Similar Songs