Monkey Wear Shoe
3
views
Lyrics
Ìbàse'jẹ' awo sọ'lúdìgbẹ' o Làntìlanti, pàtàn lábẹ' ewé Ìlú òkè ni mo lọ, ó ti gbé'lé yẹn tà o Ọmọ àpà li wọn ńpè 'rú rẹ o Ìbàse'jẹ' fọ'tẹ'sọlá o Ọ'rọ' rẹ ní mo rò d'ọ'dọ' àgbà Iye sunkún, bàbá f'ọwọ' lẹ'rán o Wọn l'ọmọ ènìyàn wọn ò ṣe gb'ára lé o Monkey dey wear shoe, e think say e be fine guy Alábòsí, ọ'rẹ' túlétúlé Wòòkòwooko, ẹ ò r'ójú olè Ìwà ibi ni ò jẹ' o r'álájọgbé Gbogbo ń kán ò mà lè jẹ' tìrẹ o Ìbùsọ' l'ẹnu ká ti jẹun k'á yó Ọ'rọ' ọ'fun lo má ń f'orí rẹ rò Àgbà ọmọ a ṣe bíi màjèsín o Ìgba kan ò lọ bí òréré o Ọ'sán bá ọ wí, o lóò ní gbọ' Alẹ' bá ọ sọ', o l'ẹ'nu rẹ' ń rùn Aleni ṣọ'lẹ, olè ní ó jà gbẹ'hìn Ha, ń bá mọ' ní kẹ'hìn aṣebi o Monkey dey wear shoe, e think say e be fine guy Ènìyàn méjì ìí pàdánù irọ' B'ẹ'ni a pá fún ò mọ', ẹni npurọ' mọ'ra rẹ' o Ṣèb'ójú àwo l'àwo mí fi ń gb'ọbẹ' o Ńwe ṣ'ọdẹ', mo kàn dákẹ' ni o Ènìyàn o ṣ'áwọn ná k'ẹ'ṣin l'ọ'ró Jẹ'jẹ' mí ní mo má ń lò'gbà ìwà Ẹni tọ' mi, ṣe nìyẹn ń tú 'lé agbọn o Bí ò ṣọ'ra yíó ma j'íjó ẹ'tẹ' o Ilẹ' bá ọ sọ', o lóò ní gbọ' Òkè bá ọ wí, o l'ẹ'nu rẹ' ń rùn Se'beni ení ṣọ'lẹ, k'olè ni ó jà gbẹ'hìn Ò bá tẹ'pá mọ'ṣe, ọ'la nbọ' wá da o ♪ Ìbàsẹ'jẹ' awo sọ'lúdìgbẹ' o Làntìlanti, pàtàn lábẹ' ewé Ìlú òkè ni mo lọ, ó ti gbé'lé yẹn tà Ọmọ àpà li wọ'n npe 'rú rẹ o Mo ṣe b'ọmọ apá lì wọn pé irú rẹ o Mo l'ọmọ apá lì wọn pé irú rẹ o Mo ṣe b'ọmọ apá lì wọn pé irú rẹ o Ọmọ apá lì wọn pé irú rẹ o Mo ṣe b'ọmọ apá lì wọn pé irú rẹ o Al'ọmọ apá lì wọn pé irú rẹ o Mo ṣe b'ọmọ apá lì wọn pé irú rẹ o Al'ọmọ apá lì wọn pé irú rẹ o Mo ṣe bí ọmọ apá lì wọn pé irú rẹ o
Audio Features
Song Details
- Duration
- 04:31
- Key
- 4
- Tempo
- 118 BPM
Share
More Songs by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Albums by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Similar Songs
Araromi
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Atunda Ere
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Gedegbe
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Ijo Oni
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Abanije
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Afurugbin
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band