Oloja

4 views

Lyrics

Mo k'áwo s'ọjà nṣ'ajé
 Agbéwiri f'ẹsọ kó wọn lọ
 Ó l'ọba ló mà rán 'un ní'ṣẹ olè
 Ojú mi pàkò ńwòran
 A gbọ'kà sí'lẹ ká jẹun, ah, ká fi'un sínú
 Ọlọ'bùn yí pẹ'tẹ k'ọwọ sí'nú rẹ o, ah, pọ'ṣọ-pọ'ṣọ
 Abọ'nisíhòhò tí ńf'ewé bo tirẹ
 Ẹnu mi sùtì ò r'ọrọ sọ
 Onísùúrù é mà í ṣe t'ọdẹ o
 Àní ka má jà ló jù o
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ah, ẹ la ni, ẹ gba ni, oh
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni o, ẹ la ni, ẹ gba ni, ye o
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni o, ẹ la ni, ẹ gba ni, ye o
 ♪
 A gbé'lù sí'lẹ ká ṣe'ré
 Wọn l'áwọn l'ó kàn láti jó l'ágbo
 Ẹlẹ'sẹ' mẹ'rìnlá fi mú fọn fèrè
 Etí mi fẹ'nfẹ ò f'áriwo
 Onísùúrù yi é mà í ṣe t'òmùgọ o
 Àní, ka má jà ló jù o
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni, oh
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni o, ẹ la ni, ẹ gba ni o, ye o (ojú mi pàkò ńwòran)
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni (enu mi sùtì ò r'ọrọ sọ)
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni, ye o (etí mi fẹ'nfẹ ò f'áriwo)
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni, oh
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni o, ẹ la ni, ẹ gba ni o, ye o (ojú mi pàkò ńwòran)
 Ha-ha-ha-ha, yé, Ọlọ'jà, ẹ gba ni, ẹ la ni, ẹ gba ni, ye o (enu mi sùtì ò r'ọrọ sọ)
 Ha-ha-ha-ha-
 

Audio Features

Song Details

Duration
03:44
Key
1
Tempo
101 BPM

Share

More Songs by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

Albums by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

Similar Songs