Omoagba
3
views
Lyrics
Ọmọàgbà, ṣèb'ó ti dé'lé owó o Má mà ṣe ṣì'wà wù, má jẹ'un wọmù-wọmù bí àlejò Ye o, ọmọàgbà, à l'o ti wọ'lé ọlá o Má mà ṣe ṣì'wà wù, má tẹ'lẹ' jàù-jàù bí àjèjì o Tere, te, re-re ♪ Ẹniábiire kìí bínú òdì Oníwàtútù, ẹni're ni Ọmọlúwàbí, abánitọ'mọ o, atúnlù'tò, ọmọ ọkọ, eh, eh Eh, ọmọàgbà, ṣé bo ti wọlé owó o Má-mà ṣe ṣì'wà wù, má jẹ'un wọmù-wọmù bí àlejò Ye o, ọmọàgbà, à l'o ti délé àgbàrá o Má-mà ṣe ṣì'wà wù, má tẹ'lẹ' jàù-jàù bí àjèjì o ♪ Ẹni è tó fún, wọn ń bẹ l'óde o Àwọn yẹn ń wo'jú Ọlọ'run l'ókè, Ọba ní Ẹni ò rí b'átiṣé, bi wọn pọ' ní'ta Àwọn yẹn ń wo'jú Elédùmarè, kó dáhùn Ọmọàgbà, aa lo tí wọlé ọlá o Má-mà ṣe ṣì'wà wù, má jẹ'un wọmù-wọmù bí àlejò Ye o, ọmọàgbà, à l'o ti délé àgbàrá o Má mà ṣe ṣì'wà wù, má tẹ'lẹ' jàù-jàù bí o ♪ Ẹni ábiire, kìí bínú òdì Oníwàtútù, ọmọ ọkọ' ní Ọmọlúwàbí, abánitọ'mọ o, atúnlù'tò, ẹní 're Ọmọàgbà, ṣèb'ó ti dé'lé owó o Má-mà ṣe ṣì'wà wù, má jẹ'un wọmù-wọmù bí àlejò Ye o, ọmọàgbà, à l'o ti wọ'lé ọlá o Má-mà ṣe ṣì'wà wù, má tẹ'lẹ' jàù-jàù bí àjèjì o ♪ Má jẹ'un wọmù-wọmù bí àlejò ♪ Má tẹ'lẹ' jàù-jàù bí àjèjì Ye o, ọmọàgbà ♪ Má jẹ'un wọmù-wọmù bí àlejò ♪ Má tẹ'lẹ' jàù-jàù bí àjèjì Ye o, ọmọàgbà ♪ Má jẹ'un wọmù-wọmù bí àlejò ♪ Má tẹ'lẹ' jàù-jàù bí àjèjì
Audio Features
Song Details
- Duration
- 04:35
- Key
- 11
- Tempo
- 93 BPM
Share
More Songs by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Albums by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Similar Songs
Araromi
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Atunda Ere
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Afurugbin
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Gedegbe
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Ijo Oni
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Se'untoose
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band