Songs Of The Trickster

7 views

Lyrics

Ìlù mi dún kẹ'kẹ'kẹ'
 Ìlù mi dún kàkàkà
 Ìlù mi s'ọ'rọ' ẹnu rẹ kí ngbọ'
 Ọmọdé mẹ'ta nṣ'eré (eré o, eré ayọ')
 Ọmọdé mẹ'ta nṣ'eré (eré o, eré ayọ')
 Ọ'kan l'óun ó wẹ"kun (eré o, eré ayọ')
 Ọ'kan l'óun ó g'ọ'pẹ (eré o, eré ayọ')
 Ọ'kan l'óun ó tà'run (eré o, eré ayọ')
 Ọ'wẹ'kun, ọ'wẹ'kun, ọ'wẹ'kun (eré o, eré ayọ')
 Ọ'gọ'pẹ, ọ'gọ'pẹ, ọ'gọ'pẹ (eré o, eré ayọ')
 Ọ'tàrun, ọ'tàrun, ọ'tàrun (eré o, eré ayọ')
 Ani, réré o, réré ọmọ olúwo (àgbámùréré)
 Réré o, réré ọmọ olúwo (àgbámùréré)
 Ìyá f'ewúrẹ' lẹ', ó ní nkọ"dẹ ṣe (àgbámùréré)
 Bàbá f'àgùntàn lẹ', ó ní nkọ"dẹ ṣe (àgbámùréré)
 Mo l'ó d'igbó ẹfọ'n, ó d'igbó erin (àgbámùréré)
 Àgbàrá òjò l'ó fà mí l'ẹ'sẹ', mo yẹ' gẹ'rẹ'
 Mo yẹ' gẹ'rẹ' s'ódò, mo bá d'ẹrú ahun (àgbámùréré)
 Ahun gbé mi s'ílù, ó ní nmáa kọ'rin (àgbámùréré)
 Ani, réré o, réré ọmọ olúwo (àgbámùréré)
 Mo rí kẹ'kẹ' kan (gbinrin, àjàlóbalẹ', gbinrin)
 Mo ma rí kẹ'kẹ' kan (gbinrin, àjàlóbalẹ', gbinrin)
 Òpobípobí (gbinrin, àjàlóbalẹ', gbinrin)
 Òpobìpobì (gbinrin, àjàlóbalẹ', gbinrin)
 Orípolóbì o (gbinrin, àjàlóbalẹ', gbinrin)
 Ani mo rí kẹ'kẹ' kan (gbinrin, àjàlóbalẹ', gbinrin)
 Òpobípobí (gbinrin, àjàlóbalẹ', gbinrin)
 Òpobìpobì (gbinrin, àjàlóbalẹ', gbinrin)
 Orípolóbì o (gbinrin, àjàlóbalẹ', gbinrin)
 Take me back to the place of merry-tales
 Where we'll roam in happiness
 We'll be riding aloft
 On magical adventures
 Fix me up in your world of no pretense
 We'll be innocent again
 We'll be riding aloft
 On magical adventures and make-believe
 Take me back to the place of merry-tales
 Where we'll roam in happiness
 We'll be riding aloft
 On magical adventures
 Fix me up in your world of no pretense
 We'll be innocent again
 We'll be riding aloft
 On magical adventures and make-believe
 Ìlù mi dún kẹ'kẹ'kẹ'
 Ìlù mi dún kàkàkà
 Ìlù mi s'ọ'rọ' ẹnu rẹ kí ngbọ' (kí ngbọ', kí ngbọ', kí ngbọ')

Audio Features

Song Details

Duration
05:06
Key
1
Tempo
85 BPM

Share

More Songs by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

Albums by Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

Similar Songs