How do you do? (Owuro L'ojo)

8 views

Lyrics

Ojúmọ' tí mọ, ará mí, ẹ gbéra nílé, ìṣẹ tí ya
 Ojúmọ' tí mọ, ọ'rẹ' mí, ẹ gbọn'ra jìgì, kà tun'ra mu
 Oníṣẹ́ ọwọ, alakọ'wé, gbogbo ẹni to ń wáṣẹ, ọmọ'lewe o
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o

 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o, let's go my beautiful sisters
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o
 ♪

 Jẹ a ṣe'bà òwúrọ̀ o, let's go once again
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o
 ♪
 Good morning, I greet you
 How do you do?
 Good morning, I greet you
 We've got some work to do
 Good morning, I greet you
 How was your night?
 Good morning I greet you
 It will be a beautiful day
 If you do your work
 With honesty and pride
 You will find your dreams coming true very soon
 Said if we could be patient
 And live within the law
 There will be much progress, everyone will be happy
 Good morning, I greet you
 How do you do?
 Good morning, I greet you
 We've got some work to do
 Good morning, I greet you
 How was your night?
 Good morning, I greet you
 It will be a beautiful day
 ♪
 Ojúmọ' tí mọ, ará mí, ẹ gbéra nílé, ìṣẹ tí ya
 Ojúmọ' tí mọ, ọ'rẹ' mí, ẹ gbọn'ra jìgì, kà tun'ra mu
 Oníṣẹ́ ọwọ, alakọ'wé, gbogbo ẹni to ń wáṣẹ, ọmọ'lewe o
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Ẹ mà jẹ à ṣe'bà òwúrọ̀ o, let's go beautiful people
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o
 One more time, owúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o (oohh)
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Jẹ a ṣe'bà òwúrọ̀ o

 (Let's go again) òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà ríré o, ẹní mà ríré o
 Wọn a ṣe'bà òwúrọ̀ o
 Òwúrọ̀ lọjọ ẹní mà rí rẹ-
 
Audio Features

Song Details

Duration
05:59
Tempo
153 BPM

Share

More Songs by Beautiful Nubia

Albums by Beautiful Nubia

Similar Songs