Muku-i-muku
3
views
Lyrics
Muku-I-muku It's so nice to see people come together To share love and happiness in a place of harmony And the children – singing, dancing, chanting Ore e wa, e je k'a lo, ore e wa Ore e ba mi kalo l'agbo Beautiful Nubia Seb'orin la nko nibe, seb'ijo la njo nibe o Ara e ba mi kalo l'agbo Roots Renaissance Seb'ere la nse nibe Ko si wahala ni'bi rara Ni muku i muku – ni mukulumuke Ni wemu, ni wemu Omode nbe nibe, awon agbagba o gb'eyin nibe Omobinrin po jaburata, awon omokunrin o gbe'yin Rara Alakowe nbe nibe, awon onise owo nbe nibe Awon agbe o gbe'yin nibe, omo'lewe po jaburata o Olomoge nbe nibe, awon iyawo'le wa nibe Alaboyun po nibe, mama agba ro'ro ofi won jo Ore e ba mi kalo... B'ebo ba di gbigba, ijo l'o ye wa Adura wa gba, erin l'o ye wa B'ebo ba di gbigba, ilu yi a toro B'ebo ba di gbigba, aye wa a toro mini Logged Genius is more work than genius.
Audio Features
Song Details
- Duration
- 04:50
- Tempo
- 156 BPM