Atonisona

7 views

Lyrics

Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (l'órí òkè, wọn tún gbe dé)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (l'ọwọ' ìsàlẹ', wọn tún gbe dé o)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'ọlọgbọn o, pọn tún ti dé o)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'áwọn amòye, pọn tún ti dé o)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e
 K'á ma fì'fẹ' lò, k'á ma wù'wà 're
 K'á mú'ra s'óhun tí ó tún ìlú ṣe
 K'á má ṣe sọ' irètí nù, k'á so'wọ' pọ' k'ó dára
 ẸniỌbánkẹ', atọ'nisọ'nà ìyè
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (l'étí òkun o, wọn tún gbé dé)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ní'nú aginjù, wọn tún gbe dé o)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'ọmọdé o, pọn tún ti dé)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'áwọn àgbà, pọn tún ti dé)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e
 Wọn ní k'ọmọ s'òtítọ', kó má ṣe s'àìgbọràn
 Kò má ṣe ṣá'ìgbọràn, k'ó mú'ra sí iṣẹ' rẹ' l'áti kékeré
 K'á má ṣe k'ẹgbẹkẹgbẹ, k'á má ma ṣè'gbéraga
 ẸniỌbánkẹ', a kọmọ ní'wà ìrẹ'lẹ'
 ♪
 Wọn ní k'a s'òtítọ', k'á ma wù'wà 're
 K'á mú'ra s'óhun tí ó tún 'lẹ' yì ṣe
 Wọn ní k'a f'òtẹ' s'ílẹ', k'a fì'wà ṣ'ọlá gẹngẹ
 ẸniỌbánkẹ, a fún ni l'órò àgbà
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o (ní'bi kòrò, wọn tún gbe dé)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o (ní gbangba o, wọn tún gbe dé o)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o (ké s'ọ'kùnrin o, pọn tún ti dé o)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o (ké s'áwọn obìrin o, pọn tún ti dé)
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbọ' tuntun o, yeah e
 Ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e
 Yeah e, ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e
 Yeah e, ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e
 Yeah e, ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o, yeah e
 Yeah e, ará, ẹ wá, ẹ wá gbó tuntun o
 

Audio Features

Song Details

Duration
04:34
Key
2
Tempo
155 BPM

Share

More Songs by Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band

Albums by Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band

Similar Songs