Ma Gbagbe Iwa

6 views

Lyrics

Ọmọ sọ' 'wà nù, ó l'óun ò l'órí ọkọ
 O ò lè bá 'gún jẹ ko fẹ' b'ẹ'yẹlẹ' tò pọ'
 Kò s'óun tá ò ṣ'iṣẹ' fún tí mọ' ni l'ọwọ
 Ìfẹ' àti sùúrù ló mà ṣe pàtàkì
 K'o má gbàgbé ìwà o
 Má gbàgbé òtítọ' o
 B'o ṣe ń jáde lónì oh-oh, oh, oh
 Ani, k'o má gbàgbé ìwà
 Ilé aiyé asán, kìí ṣ'àdìmọ'yà
 Ko s'óun t'o ní t'ó mú kúrò níbẹ'
 Bo dé'bi gíga, k'o tẹ'lẹ' jẹ'jẹ'
 Ìtẹ'lọ'rùn, ìṣọ'ra ló mà ṣe pàtàkì
 K'o má gbàgbé ìwà
 Má gbàgbé ìfẹ' o, oh-oh, oh, oh
 B'o ṣe ń wọ'lé lónì o, oh-oh
 Àní, k'o má gbàgbé ìwà o
 Ọlọ'jọ' ń ka'jọ, ẹ'dá gbàgbé ọ'nà
 Wọ'n ṣe b'ádé orí ni yíò gbé wa dé èbúté ayọ'
 Ahh, olọ'jọ' ń ka'jọ' ẹ'dá gbàgbé ọ'rọ' ìpìlẹ'
 Wọ'n ṣe b'ọwo ni yíò gbé wa d'óde ìfọ'kànbalẹ', oh
 Ọlọ'jọ' ń ka'jọ, ẹ'dá gbàgbé ọ'nà otito
 Wọn ṣe b'àgbàrá ni yíò gbé wa dé èbúté ayọ'
 Olọ'jọ' ń ka'jọ' ẹ'dá gbàgbé ọ'rọ' ìpìlẹ'
 Wọn ṣe b'ọ'la ni yíò gbé wa d'óde ìfọ'kànbalẹ'
 Ọlọ'jọ' ń ka'jọ', ẹ'dá gbàgbé ọ'nà
 Wọn ṣe b'adé orí ni yíò gbé wa dé èbúté ayọ'
 Olọ'jọ' ń ka'jọ' ẹ'dá gbàgbé ọ'rọ' ìpìlẹ'
 Wọn ṣe b'owó ni yíò gbé wa d'óde ìfọ'kànbalẹ', oh
 K'o má gbàgbé ìwà o
 Má gbàgbé òtítọ' o, oh-oh, oh, oh
 B'o ṣe ń jáde lónì o, oh-oh, oh, oh
 B'o ṣe ń wole bọ
 Nibi'ṣẹ rẹ, ọ'rẹ'
 Ni ilé ìwé o
 Níbí te ń gbé Kórà jọ jẹ̀gbádùn
 Àbí tó bà dá nìkan wa
 K'o má gbàgbé ìwà o
 Ọ'rẹ' mí, má gbàgbé ìwa o
 Má gbàgbé ìwà o
 K'o má gbàgbé ìwà o
 Ọ'rẹ' mí, má gbàgbé ìwa o
 K'o má gbàgbé ìwà o
 K'o má gbàgbé ìwà o
 Má gbàgbé ìwà o
 Ọ'rẹ' mí, má gbàgbé ìwa o

Audio Features

Song Details

Duration
05:07
Key
3
Tempo
101 BPM

Share

More Songs by Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band

Albums by Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band

Similar Songs