Sa Ma Jo

3 views

Lyrics

Ẹ sá ma jó o
 Sá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ s'égbẹ òsì
 Má wo'jú ẹnìkan o
 Ani o ṣá ma jó
 Ṣá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ s'égbẹ òsì
 Má wo'jú ẹnìkan o
 B'ówó ń bẹ l'ọwọ, a ó jọ lò'gbà yí pẹ' ni
 Bí ò sí o, àwa ò mà ní sọ' 'rètí nù
 B'ówó ń bẹ l'ọwọ, a ó jọ lò'gbà yí pẹ' ni
 Bí ò dẹ sí o, àwa ò mà ní sọ' 'rètí nù
 Ṣá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó yẹn s'égbẹ òsì
 Má wo'jú ẹnìkan o
 Ṣá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó yẹn s'égbẹ òsì
 Má wo'jú ẹnìkan o
 ♪
 Ohunkóhun tó wúwo l'ọ'kàn ká fì yẹn s'ílẹ'
 Kò mà s'óun tó lè ṣelẹ' tá ò rí rí o
 Àní kí o gbé 'ra n'ílẹ' k'o sọ 'tìjú nù
 Ẹni tó nbẹ l'álàáfíà ó mà l'óun gbogbo
 Ará mi ẹ dìde, ẹ jẹ' ká fi'jó si, ká tú'raká o
 Ijó ayọ' ni, ijó aládùn tó lárinrin
 Ah, gbogbo ayé la pè o, kò mà s'ẹ'ni tí ò ní le kó'pa
 Ẹ jó ẹ yọ' o, ẹni 'nú rẹ' bá dùn kó ṣe bẹbẹ
 ♪
 Ṣá ma jó o
 Sá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ s'apa òsì
 Má wo'jú ẹnìkan o
 Ṣá ma jo o
 Ṣá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ s'égbẹ òsì
 Má wo'jú ẹnìkan o
 ♪
 Ohunkóhun tó wúwo l'ọ'kàn ká fì yẹn s'ílẹ'
 Kò mà s'óun tó lè ṣelẹ' tá ò rí rí o
 Àní kí o gbé 'ra n'ílẹ' k'o sọ 'tìjú nù
 Ẹni tó nbẹ l'álàáfíà ó mà l'óun gbogbo
 Ará mi ẹ dìde, ẹ jẹ' ká fi'jó si, ká tú'raká o
 Ijó ayọ' ni, ijó aládùn tó lárinrin
 Ah, gbogbo ayé la pè o, kò mà s'ẹ'ni tí ò ní le kó'pa
 Ẹ jó ẹ yọ' o, ẹni 'nú rẹ' bá dùn kó ṣe bẹbẹ
 ♪
 'Ni o sá ma jó o
 Ṣá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ s'apa òsì
 Má wo'jú ẹnìkan o
 Ṣá ma jo o
 Ṣá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ s'égbẹ òsì
 Má wo'jú ẹnìkan o
 B'ówó ń bẹ l'ọ'wọ', a ó jọ lò'gbà yí pẹ' ni
 Bí ò sí o, àwa ò mà ní sọ' 'rètí nù
 B'ówó ń bẹ l'ọ'wọ', a ó jọ lò'gbà yí pẹ' ni
 Bí ò sí o, àwa ò mà ní sọ' 'rètí nù
 Ah, sá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ s'apa òsì
 Má wo'jú ẹnìkan o
 Ṣá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ s'égbẹ òsì
 Ma wo'jú ẹnìkan o
 Ṣá ma jó o
 ♪
 Ṣá ma jó o
 ♪
 Sá ma jó, sá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ segbe osi
 Má ma wo ju enikan o
 'Ni o sá ma jó, sá ma j'íjó yẹn s'ẹ'gbẹ ọ'tún, k'o j'íjó ẹ segbe osi
 Ma wo ju-
 
Audio Features

Song Details

Duration
05:33
Key
11
Tempo
123 BPM

Share

More Songs by Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band

Albums by Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band

Similar Songs