Eleko’Dere

8 views

Lyrics

Eleko'dere ṣebo o lo jere
 Eleko'dere ṣebo o lo jere
 Eleko'dere ṣebo o lo jere
 Eleko'dere ṣebo o lo jere
 O n ro'ṣọ dudu, o si n ro'ṣo pupa
 O n ro'ṣo dudu o si n ro'ṣo funfun
 O faimu gbaja o si tun lekenka o
 Eleko'dere ṣebo o lo jere
 Eleko'dere ṣebo o lo jere
 Eleko'dere ṣebo o lo jere
 Eleko'dere ṣebo o lo jere
 Eleko'dere ṣebo o lo jere
 O n ro'ṣọ dudu, o si n ro'ṣo funfun
 O n ro'ṣo dudu o si n ro'ṣo pupa
 O faimu gbaja o si tun lekenka o
 Eleko'dere ṣebo o lo jere
 Asiko Eledumare lo dara
 (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ)
 Asiko Eledumare ni yẹni
 (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ)
 Ani ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ
 (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ)
 Asiko Eledumare lo dara
 (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ)
 Ọrẹ ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ
 (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ)
 Kii ṣe ti ka joko jẹbẹtẹ
 Kii ma i ṣe ti ka joko rẹgẹdi
 Iṣẹ ń bẹ pupọ lati ṣe
 Kii ma i ṣe ti ka joko bẹbẹrẹ
 Kii ṣe ti ka joko rọbọtọ
 Iṣẹ ń bẹ nilẹ lati ṣe
 Asiko Eledumare lo dara
 (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ)
 Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ
 (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ)
 Asiko Eledumare ni yẹni
 (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ)
 Ani ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ
 (Ka f'oun gbogbo s'Ọba mimọ lọwọ)
 Asiko ti to ara mi o, asiko ti to
 Asiko ti to ara mi o, asiko ti to
 Asiko ti to fun wa o
 Ara mi, asiko to to fun wa o
 Ka bo l'oko ẹru (asiko ti to fun wa o)
 Ka bọ'wu iya sọnu (asiko ti to fun wa o)
 B'iṣẹ o ba pẹni o (asiko ti to fun wa o)
 Ṣeb'ẹnikan i pẹ'ṣẹ (asiko ti to fun wa o)

 Asiko ti to fun wa (asiko ti to fun wa o)
 Asiko ti to fun wa ...
 
Audio Features

Song Details

Duration
04:37
Key
2
Tempo
99 BPM

Share

More Songs by Beautiful Nubia

Albums by Beautiful Nubia

Similar Songs