JowaBayi

2 views

Lyrics

(It's Dami Records, baby)
 Orororororo
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Ọmọ, jowa bayi (jowa bayi)
 O ṣé n ṣe bayi? (Jowa bayi)
 Oun rin mii (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Bo ṣe n gbe wa na ni mo ún gba lẹnu, ahn-ahn
 Àwọn ọmọ Peckham wọn ma ta lẹnu, ahn-ahn
 Tọ ba sa'ṣẹ, always working, always sighting, always moving
 Always sporting, always popping, always sa'ṣẹ, uh
 Are you paying, fam? Are you paying, fam? Fuck
 Oya, move, move, what the fuck?
 Make you waka well, má lọ fall
 Oya pa'na oju kan, ko ma fi kan riran
 O ṣá mọ pe emi gan mo le fikan di-
 Má lọ b ami faa tori owo mi
 Oya, tẹ-tẹ, joro mi
 Anything to ba fẹ ni ma fun ẹ, fun ẹ
 Baby, jọọ, ma sọ fun mi pe oti rẹ-rẹ
 'Cause I'm ready lati, oya, press ee
 Even though, to ba fun mi laye, maa run ẹ, run ẹ
 Abi kẹ, ah, mo dẹ le fun ẹ, fun ẹ
 Óṣá mọ, ah, man's not hot, hmm, ah, man's not hot
 Óṣá mọ, ah, man's not hot, hmm, ah, man's not hot
 Óṣá mọ, ah, man's not hot, hmm, ah, man's not hot
 Óṣá mọ, ah, man's not hot, hmm, ah, man's not hot
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Ọmọ, jowa bayi (jowa bayi)
 O ṣé n ṣe bayi? (Jowa bayi)
 Oun rin mii now (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Killing the beat, Mystro, Mystro, Mystro
 All my London girls don start to denge pose (denge pose)
 If you hear the gbẹdu make you bẹ'rẹ' jo (bẹ'rẹ' jo)
 Mystro lele yi (ye), ijo onijo lele yi (yea)
 If you want to get the pounds geti down, eh-eh
 Owo n bẹ lapo (eh), ijo yera wo (ah)
 Agege wa ni London làwọn Peckham n yẹ rawo
 Jojo le to dey ba mi jo (wọn bami jo)
 Jojo le to dey jisoro
 Rekete, rekete (yan, yan, yan)
 Kpekele, kpekele (yan, yan, yan)
 Wiggle the thing, wiggle the thing, Aunty Ruth dey we gèlè (yeba)
 Darami kpekete (gbum-gudugumgudugum)
 360 kpekele (gbum-gudugumgudugum)
 Eh, Mystro leleyi o (eh)
 Jo, Shakira, idi lo rọ toyi
 Jo Rahmoni, Jago, ma pa mi na
 Hmm-ah, pepper sneh, shout out to Baddo Sneh
 Hmm-ah, pepper sneh, shout out to Baddo Sneh
 Hmm-ah, they don't know shi', wọn nipe a ń jijo òṣì
 Hmm-ah, they don't know shi', won nipe a ń jijo òṣì
 Hmm-ah, man's not hot, you know say man's not hot
 Hmm-ah, man's not hot, you know say man's not hot
 Nii gba, ni kọrọ
 Nii gbangba, ni kọrọ
 Gbas, gbos, ni kọrọ
 Nii gbangba, ni kọrọ
 Ṣí 'gẹ, ṣí gẹgẹ
 Bo gbe mu ẹ, ṣí gẹgẹ
 Le wọn, le wọn lérè
 Bọ yọ'go, ẹ yọ lẹbẹ
 Leave am, fi lẹ be
 Don't touch am, fi lẹ be
 That's my, that's my bae
 Don't touch am, that's my bae
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 Ọmọ, jowa bayi (jowa bayi)
 O ṣé n ṣe bayi? (Jowa bayi)
 Oun rin mii now (jowa bayi)
 Jowa bayi (jowa bayi)
 (Jowa bayi)
 

Audio Features

Song Details

Duration
03:37
Key
1
Tempo
125 BPM

Share

More Songs by Damibliz

Albums by Damibliz

Similar Songs