Akure Nile

4 views

Lyrics

Akure n'ile to l'oye mekun
 Omo bi d'ale m'ogun erun pa ni
 Akure l'omi meji, won pe ejeji ala
 Ala sebire bire, ala d'omi ebo
 Akure n'ile to l'oye mekun
 Akure n'ile to l'oye mekun
 ♪
 N'ile ni Barrister Lawyer Faloye mi
 International Barrister
 Awon Lawyer r'aja k'aye
 Ajanaku ti m'igbo kijikijikiji
 Eda to ba l'ejo, to ba fe gba lawyer
 Ko lo ri Faloye mi
 Eda to ba ni case, to ba fe gba lawyer
 Ko lo ri Faloye mi
 Barister Lawyer rere
 Ako n'iwaju adajo
 A s'ejo e fun e leto leto se o n gbo
 N'ipari ejo wan a da e lare o
 Barrister Lawyer l'awa n fe
 Koja l'eti ri, wan da e lare o
 Ni gelele ma ba wan debe o jare
 Akure n'ile to l'oye mekun o
 N'ile Iasaac Babalola oko Florence
 Akure n'ile to l'oye mekun o
 Babalola, baba Olusegun o omo ni
 Akure n'ile to l'oye mekun o
 Bank Manager, Babalola mi o ti wa ni
 Akure n'ile to l'oye mekun o
 

Audio Features

Song Details

Duration
02:45
Key
5
Tempo
117 BPM

Share

More Songs by King Sunny Ade

Albums by King Sunny Ade

Similar Songs