Yeyeye
6
views
Lyrics
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o ♪ A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) Ọ'dọ'mọdé wọn ìí gbọ' 'kú aṣọ, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) Àwọn àgbàlagbà wọn ìí gbọ' 'kú aṣọ o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ó d'ogbó o, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) ♪ Ọmọdé yìí onínú-ire Bo jáde ní'lé, ibi ò ní kàn ọ' o Bo bẹ'rẹ' l'óko, o ò ní d'àwátì Ìbàlẹ' ọkàn ni t'aṣòótọ' o A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) Bá a bá ṣe rere, à pẹ' bí ọ'pẹ (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) Bí igi ìrókò tí nbo'lé b'àlejò (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ó d'ogbó o A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) ♪ A ì gbọ' 'kú ọkọ', a ì gbọ' 'kú àdá o A ti já'wé gbígbó ká a má nù l'éwe A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) Ọ'dọ'mọdé wọn ìí gbọ' 'kú aṣọ, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) Àwọn àgbàlagbà wọn ìí gbọ' 'kú aṣọ o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ó d'ogbó oo A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ò ní d'àgbà òṣì a tọrọ jẹ (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ò ní d'àgbà ọ'dẹ' à mú ṣe yẹ'yẹ' o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ò ní d'àgbà-yà ọ'dagború (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) A ó d'ogbó o A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) ♪ (Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó) Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Audio Features
Song Details
- Duration
- 04:42
- Key
- 7
- Tempo
- 138 BPM
Share
More Songs by Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band
Albums by Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band
Similar Songs
Atonisona
Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band
Sore
Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band
By the Lake
Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band
It's All Here
Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band
Truly, Deeply
Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band
Yeyeye
Beautiful Nubia & The Roots Renaissance Band