Hustling (Skit)

3 views

Lyrics

Yo, mo ran ti igba kan, ti ma n kiri
 Ti mba de lati school, mehn, mi mo sun kiri
 Ti m ba langadi p'ewo leni, mi o fe kiri
 Ma je atori, ma stool down, ese mi ko de gbodo kan ogiri
 Ki lo fe nile aiye yii, ti mi o ti kiri?
 Mo ti kiri ewa, elubo, garri, tanfiri
 Igba kan ti e tun wa, ti mo n tun se onidiri
 Oni fe believe, tim ba ba iyawo e diri
 I'ma sharp boy, mi o bolo, mi o shadin
 O je ka won eniyan ma wa mi kiri bi ti Bin-Ladin
 Nigba ti mo wa ni 14 years old si 15
 Momsi ma n pe, "Ola you're good for nothing"
 Mo fe prove won wrong, mo lo gbe won ni ike owo ni canteen
 Won fe lu mi pa, mo lo pephensic, mo support e pelu pilatrin
 Yeah, that's how it's, yo, still on the matter
 

Audio Features

Song Details

Duration
00:36
Key
1
Tempo
103 BPM

Share

More Songs by Dagrin

Similar Songs