Aye Yii
3
views
Lyrics
Aye aye (Aye e e o o o o) This world eeh (hmn hmn hmn hmn oh this world, aye yi) Aye aye (Aye e e o o o o) This world eeh (hmn hmn hmn hmn oh this world, aye yi) (This world, aye t'a wa yi o) Nitori aye - eda gbagbe Olorun Nitori aye - eeyan gbagbe iku o Aye yi, aye eh - aye eh eh ah ah ah aye yi Eniyan fe aye, aye o feran won Won ni aye n d'ogbo, aye o kuro, eniyan lo tun s'aye di tuntun Aye ja gba lowo eeyan o fi tun 'ra e se, eda o mo ja gba lowo aye k'on fi t'orun won se Eda gbagbe oh eh, eniyan gbagbe o P'aye yii kii se t'eniyan Eda wa na'ja laye ni Aye aye (Aye e e o o o o) This world eeh (hmn hmn hmn hmn oh this world, aye yi) Ara ki lo n wa, t'o n wa to bee t'o n sa kijo kijo Ore ki lohun to mu wa, t'o fe di pada lo, tell me I want to know Aye n w'owo, tori e pa'ra won lekun, ah o se Tori ile, tori aso, alumoni oro repete, eniyan tori agbara di kiniun, ikoko ajorijapa Won a ma bu ramuramu, a di iduro o si, ibere o si o, bi eni to gb'odo mi Aye aye (Aye e e o o o o) This world eeh (hmn hmn hmn hmn oh this world, aye yi) Eniyan lo n p'aye, aye o p'eeyan Eda n fe'fun p'aye, aye o se kirakita Aye o se wahala (En) Eniyan lo n wo laasigbo (Oin) S'enu jeje mu'ti laye (En) Aye o lese, aye mirin (Oin) Eniyan n ro lese tori aye (En) Aye o loju, aye n riran (Oin) Oju eda n wa'mi tori aye (En) Aye logba eniyan lo n ro'ko e (Oin) Aye o loyun, aye n bimo (En) Omo t'eniyan n bi, aye tun n ni won (Oin) Eniyan o gbon mo pa'ye n pamo o ki iku to de La i lojo lori eniyan n gbo Aye f'arungbo ojo ori eeyan, eda lo n sise oro f'aye, t'aye fi n tuntun si lojoojo Aye d'oloro, eniyan n ku 'ku otosi Aye de gbon 'gbon akuusin Aye aye (Aye e e o o o o) This world eeh (hmn hmn hmn hmn oh this world, aye yi) Eniyan ronu o, k'aye to je o mo orun re Omo to so 'le nu, n lo so apo iya ko Olugbala ke tantan o, omo maa bo Oga ogo feran re o, omo yara wa Ara ma ko 'fe Jesu yi o, wa gba 'rapada to f'eje se This is practical love that I've ever seen in display Aye aye (Aye e e o o o o) This world eeh (hmn hmn hmn hmn oh this world, aye yi) Ife amutorunwa, igbala yi On lo le se Ona isinmi miran ko si, afi ninu ife Oluwa Ko s'eni to le fe o to Jesu Ultimate price He has paid Pansaga, agbere wa, ole, ika, e yara wa Apanilekun e sare ma bo Iborisa at'akogun ja 'lu Eyin akogun ja orile ede E gb'ohun Eleda yin, t'On f'ife pe yin o Ore ma d'aniyan si, ko ma so p'oo gbo O n pe o, omo wa gba 'gbala S'e ti r'alaso to ku ti won d'aso e mo (E je n gbo) S'e ti r'eleran to ku ti won di maalu mo (Aye e gbo) Onipetesi wo lo ku, ti won di'le e mo (K'e je a gbo) Aye agbara n f'alagbara sile, ogun a di t'awon to le jagun Oro a di t'awon ti o mo'di oro, ma fi 'gbala re sofo Aye aye (Aye e e o o o o) This world eeh (hmn hmn hmn hmn oh this world, aye yi) Aye aye (Aye e e o o o o) This world eeh (hmn hmn hmn hmn oh this world, aye yi)
Audio Features
Song Details
- Duration
- 07:44
- Key
- 11
- Tempo
- 90 BPM