Mo Mope Mi Wa

3 views

Lyrics

Oba to ku nitori mi, Oba taa pa nitori ese mi
 Oba taa kan nitori mi mo mope mi wa fun o
 Ada lebi iku, kemi le gba idalare
 Ano ni pasan, kemi maba jiya
 Oti kikan tomu, kinmaba jekoro ni
 Atuto si lara, kemi le deni aponle
 Ikoro irora toje nitori temi ni
 Oba toku nitori mi, Oba taapa nitori ese mi
 Oba taa kan nitori mi, mo mope mi wa fun o
 La layi jebi ese, asi da lebi eshe
 Isho owo ati ese re
 Pelu oko egbe re Iya eshe mi ni
 Ori ogo lofi dade egun fun emi o
 Emi o mo oun ti moja mo o
 Tofi se gbogbo iwonyi
 Mo mope mi wa
 Fun Oba to seyi fun mi
 Oba to ku nitori mi, Oba ta pa nitori ese mi
 Oba taa kan nitori mi
 Odo aguntan to k'eshe mi lo
 Oloore to gbamila o
 Ope aanu to po yi, mio riri
 Mo wa pelu emi imore
 Oba to di alaini kemi le d'loro
 Mo mope mi wa fun o Baba
 Iwo loje kopari
 Ise ati Iya to tosi mi
 Iwo loje ko tan aisan ti aarun ti nba ri
 Iwo logba kokoro iku
 Ati isa iboji ti nba wo oo
 Oba to ra iye fun mi
 Emi mo mope mi wa o oseee
 Odo aguntan to ko ese mi lo
 To somi di omo re
 Mo mope mi wa fun o
 Oba ayeraye to fi itere sile wa jiya fun emi
 Mo mope mi wa fun oo
 Owo elese ni ijoba orun
 Kole daduro omase
 Mo mope wa fun o
 Oro ayeraye to deru nitori mi
 Mo mope mi wa fun o
 Iya toje lona agbelebu manigbagbe ni mo mon
 Mo mope mi wa fun o
 Oba to laye, to lorun To Wa di alai lara
 Mo mope mi wa fun o
 Oobo ogo re kale, owaye wa gbese mi wo ooo
 Mo mope mi wa fun o
 Oro ishura ogo iyebiye
 Lofi fun mi loogun jè
 Mo mope mi wa fun o
 Iku E lori igi kafari lofi ra iye fun emi
 Mo mope mi wa fun o
 Ori ade ayeraye lofi tegun nitori mi o
 Mo mope mi wa fun o
 Emi mo riri ajinde re kemi maba shigbe ni
 Mo mope mi wa fun o
 Ore-ofe ti mo rigba lai dinyele loje nmope wa
 Mo mope mi wa fun o
 Oun gbogbo tose tose ose fun emi
 Momope mi wa fun o
 Bi mo legberun ahon
 Ko to yin o olupinl'èshè
 Momope mi wa fun o
 Alasepe igba gbo
 Olurapada ore tooto
 Momope mi wa fun o
 Momope mi wa f'eni
 To femi lati odo inu
 Momope mi wa fun o
 Oba to feran mi ju enikeni lo ooo
 Momope mi wa fun o
 Ore airi oluto okan mi, mogbope ore de
 Momope mi wa fun o
 Ope ni mo wa da oo
 Ope ni mo wa du lodo oloore mi
 Momope mi wafun o
 

Audio Features

Song Details

Duration
09:01
Key
9
Tempo
120 BPM

Share

More Songs by Tope Alabi

Albums by Tope Alabi

Similar Songs